Bibeli Mimọ Bible 2012
|
| 1 |
| AHASWERUSI ọba si fi owo ọba le ilẹ fun gbogbo ilẹ, ati gbogbo erekùṣu okun. |
| 2 |
| Ati gbogbo iṣe agbara rẹ̀, ati ti ipa rẹ̀, ati ìrohin titobi Mordekai, bi ọba ti sọ ọ di nla, a kò ha kọ wọn sinu iwe ọ̀rọ ọjọ awọn ọba Media ati Persia? |
| 3 |
| Nitori Mordekai ara Juda li o ṣe igbakeji Ahaswerusi ọba, o si tobi ninu awọn Ju, o si ṣe itẹwọgbà lọdọ ọ̀pọlọpọ ninu awọn arakunrin rẹ̀, o nwá ire awọn enia rẹ̀, o si nsọ̀rọ alafia fun gbogbo awọn iru-ọmọ rẹ̀. |
| Fipamọ Awọn akọsilẹ |
https://beblia.bible:81/BibleAudio/yoruba/esther/010.mp3
10
10