Bibeli Mimọ Bible 2012
|
| 1 |
| Ẹ fi iyìn fun Oluwa. Ẹ fi iyìn fun Ọlọrun ninu ibi mimọ́ rẹ̀; yìn i ninu ofurufu oju-ọrun agbara rẹ̀. |
| 2 |
| Yìn i nitori iṣẹ agbara rẹ̀: yìn i gẹgẹ bi titobi nla rẹ̀. |
| 3 |
| Fi ohùn ipè yìn i: fi ohun-èlo orin ati duru yìn i. |
| 4 |
| Fi ìlu ati ijó yìn i: fi ohun ọnà orin olokùn ati fère yìn i. |
| 5 |
| Ẹ yìn i lara aro olohùn òke: ẹ yìn i lara aro olohùn goro: |
| 6 |
| Jẹ ki ohun gbogbo ti o li ẹmi ki o yìn Oluwa. Ẹ fi iyìn fun Oluwa. |
| Fipamọ Awọn akọsilẹ |
https://beblia.bible:81/BibleAudio/yoruba/psalms/150.mp3
150
150